Ìfihàn Àlejò lórí ètò Ọmọlúàbì -Olaniyan Balqis

Comflo Tubetunes

28-05-2022 • 24 min

Àlejò pàtàkì láti tún gbé wà sórí ètò Ọmọlúàbì loni. Àlejò was jẹ akẹkọ gbọye láti ilé-ìwé gíga ti ijọba Obáfémi Awólọ́wọ̀ ni ìlú Ilé-Ifè. Wọn jẹ ẹni ti ọ mọ nípa káràkátà àwọn ohùn amusaraloge fún àwọn obìnrin. Wọn tún jẹ ogbontarigi ni ìdí iṣẹ Ewì ati adirẹ. É gbọ diẹ sí nínú àwọn ohùn tí a kò mọ nípa àlejò wa.